Uncategorized

OOGUN TI Ọ NYI KADARA PADA TI A FI NRI OWO

Eyin eniyan mi , ti e ba need owo , ti e ti se awon ogun ti eo ti ri nkankan, tabi eniyan ti ogun ko je lara re…..tabi eniti won ti lo kadara re, e sare lo se ogun yi, kadara naa yio pada ni kiakia !

……BASIRI OWO TI O NYI KADARA PADA TO DAJU……….
Adaripon kan, egbo tude, iru ti a ra ni oja meta, ata ijosi, ewe ati egbo peregun die, adi eyan.
Ao ju adaripon yen sinu odo laaye, ao gun kuna daada… Ao sese wa da awon eroja toku si, ao wa gun won papo kuna daada….ao wa fi owo suu nkan ti a gun yi roborobo si ona mesan fun okunrin…..meje fun obinrin.
Ao wa da adi eyan yi sinu koko kan, ao gbe sori ina….ti o ba ti gba daada, so wa ko awon nkan ti a suu roborobo yi sinu re….ao din gbe. Ao wa ko sinu awo funfun kan.
Lilo re…..ti o ba di ale ti a fe sun, ao bora si ihoho omoluabi, ao gbe awo funfun yi lowo, ao se adura si daada wipe ki won o da kadara wa pada…tabi ki a bere sini ri owo. Ao wa ma je leyo kookan. Ti a ba ti je tan, ao mu hot lee lori….ao wa lo sun.
Hmm…eyin eniyan mi…ise yi kii se ise ori facebook oo….ise inu ile ni…koda ti won ba ao wipw o lee sorire mo, iwo dan ise yi wo….ogo re toti lo, yio pada wa ni kiakia !

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published.