Uncategorized

OOGUN TI A FI NGBA KADARA WA PADA .

Hmm…mo ri wipe opolopo aisorire awon eniyan mi ko seyin awon obinrin !
Elomiran ti ba kadara ara re je lataara ibalopo. Ti eniyan ba ba awon agba sun, ti won o ba yonu si, won yio gba kadara re fun elomiran. Opolopo eniyan ni o fe alagbara eniyan sile ti o je wipe gbogbo igba ti o ba ti nbalopo ni yio ma tosi si…
Opolopo eniyan ni iyawo re ti so di olosi latari wipe ko fe ki o fe iyawo miran lee oun. Opolopo obinrin ni o ma nso wipe oun faramo ki oun ati oko oun dijo maa mu garri ki oko oun ma fe elomiran ju ki oun ma gun motor ki oko oun fe iyawo meji loo. Nkan ti ko ye irufe arabinrin bee ni wipe won yio dijo je iya naa ni.
Ti eniyan ba fe emere obinrin sile, o dara pupo sugbon ti e ba se aida tabi ti e ba fe iyawo miran, oun naa ni yio pada so oko re di olosi gbeyin aye re………
Lataara ife ti mo ni si eyin eniyan mi…itusile ti wa de bayi ………….
sare tete ki o se oogun yi ki o ja iro mi !

……….OOGUN TI ALAGBARA OBINRIN O FI NI LAGBARA LORI KADARA ENIYAN …………
tetelenje kan (omo alagba kekere) , eyo atare 7.
Sise re……ao laa ni aya, ao ko awon omo atare naa sinu re, ao wa gbe sinu ape ijoogun, ao jo.
ao lo kuna ninu ape yen.
Lilore……ao fi singbere meje si okan aya wa ..
kosi irufe alagbara ti a lee basun ti yio lagbara lori kadara wa mo ti ise yi ba wa lara wa. odaju.

elekeji………….
Ti a ba ri wipe iyawo wa ti lagbara lori kadara wa tele, nkan ti ao fi di oga lori re niyi……

………OOGUN TI A NFI LAGBARA LORI IYAWO ALAGBARA………..
omo onile aaye kan, eyo atare kan, igi ti sango pa die, ori.
Sise re………ao lo awon eroja yi ni ori olo ni deese ago kan oru. ao wa fi ori poo daada.
Lilo re…….ao ma fi pa ori oko wa ba obinrin sun.
koda ti a ba fee fe iyawo keji, obinrin naa koni lee diwa lowo tabi ki o soro rara.
sugbon mo ro eyin okunrin, e toju iyawo yin daada oo, e ma fi iya je obinrin ooo…..awon ni iya wa ooo

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published.