Uncategorized

ASEJE OWO TODAJU

Mo ranti laipe yi ti owo fe safere lowo mi die…mo wa ronu titi si aseje ti mo lee see…lakaaye mi ba so fun lekanna kinse ise kekere kan. Nigba ti mo je aseje yi tan, ni Enikan pe mi ti o si fi 70,000 naira sinu account mi lojo yen naa.
Eyin eniyan mi, inu mi dun daada lojo yen.!
Ti ko ba si idiwo lara re, ti o ba je aseje yi, dandan ni ki o ri 70,000 naira tabi jube loo
….ASEJE TI MO FI RI 70,000 NAIRA LOOJO…….
Eran malu ti a ge si 16, ewe karufinmala (ominsinminsin gogoro), ojele ewe iyalode funfun ati pupa 16- 16, ewe onitikuti 9, egbo tude die, ogede omini 3, ata ijosi 9, iyere 9. Ewe ola die.
SISE RE… ao lo awon eroja na papo daada, ao fi se eran malu yi laseje…ti a ba ti da awon eroja na si tan, ao wa bo ogede omini meteeta yi, ao ju sinu obe yi lodindi. Ao see lepo niyo.
Ti o ba ti jina, ao so sori osuka, ao gbe lo si inu yara wa. Tabi nibikan ti o pamo daada. Ao wa bu hot die sinu ideri hot yen…ao fi oti yi yika aseje yi.
Ao wa fi sile di ojo keji. Ti o ba di 5;30 ni aaro kutu ki a to. Soro si enikeni, ao se adura si aseje yi, ao sare ko je, ao si mu hot lee lori daada! Ao tun se adura ti a ba je tan.
Eyin eniyan mi, mo fe ki e sare dan ise yi wo ki e fun ile labo ni kiakia. O daju ooo
NOTE…IROLE NI TABI ALE BI 8:00 pm ni ao see aseje yio!

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published.