Uncategorized

ASEJE ASINA OWO GIDI

Taa ni o so wipe ko si oogun naa ? Boya iru enibe koiti pade eleyi ti nje laye re ni. Ti o ba de inu egbe ogbon awon agba, wa ri awon oogun tiije di ola.!

…ASEJE TI A NFI RI 200,000 TABI JUBE LOO….
Ori oka tolase lenu 1, eyo ata ijosi 9, ewe onitikuti , ewe ola ,eyin ibile 4, isasun tuntun, epo pupa.
SISE RE
Inu yara kan ni ao ti se oogun yi, ao bo ara wa si ihoho omoluabi, ao lo gbogbo awon eroja yi lotooto ni ihoho, ao fi din eyin yen pelu epo pupa.
LILO RE
Ao se adura si daada, ao sare ko je ni gbigona. Ao wa mu hot lee lori daada. Ihoho naa ni ao je oo.

Ki a to je aseje yi…..
Igbe adie inu ago, epo obo die, ao lo papo pelu ose dudu, ao lo fi we si odo tonsan.
Note….a le we ose ti ti a ba je aseje yi tan naa, kose nkankan ti ao ba we ki a to je.
aseje asina owo tipatipa ni oogun yi….koda ki owo aye wa lara re, yio sise fun e…owo yen kan le ma to iye ti mo ko soke ni…..
odaju daada.

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published.